Welcome to our Yorùbá Cooking Class!
“Ounje tó dùn l’ó ń mú kí ènìyàn rẹrìn-ín.”
Delicious food makes a person smile.
Icebreaker Questions
Kí ni orúkọ rẹ? Kí ló túmọ̀ sí? (What is your name?)
Oúnjẹ Yorùbá wo ni ẹ fẹ́ràn jùlọ? (What is your favorite Yoruba food?)
Báwo ni ọjọ́ àná rẹ ṣe rí? Kí lo ṣe? (What was yesterday like for you? What did you do?)
Kí ni ọ̀rọ̀ Yorùbá tó fẹ́ràn jùlọ? (What is your favorite Yoruba word?)
Sentence Starters
Orúkọ mi ni....
My name is…
Orúkọ mi túmọ̀ sí...
My name means…
Oúnjẹ yoruba tí mo fẹ́ràn jùlọ ni_____
My favorite Yoruba food is ______.
Ọjọ́ àná mi ṣeé rí bẹ́ẹ̀... Mo ṣe...
Yesterday was like this... I did…
Ọ̀rọ̀ Yorùbá tí mo fẹ́ràn jùlọ ni...
The Yoruba word I love most is...
Vocabulary
Nouns
àárọ̀ [ah-ah-raww]
morning
alẹ́ [ah-leh]
evening
àpò [ah-kpo]
pouch/bag
eré [ay-ray]
play
ilé [ee - lay]
house
iṣẹ́ [ee-sheh]
work
ìbìsè [ee-bee-sheh]
workplace
owó [oh-whoa]
money
ọ̀rẹ́ [aww-reh]
friend
ọ̀rọ̀ [aww -raww]
word
orin [oh-reen]
song
ọ̀sán [aww -sawwn]
afternoon
Verbs
fi [fee]
to put
gbé [gb-ay]
carry
jẹun [jeh-woon]
to eat
ní (knee)
to have
rìn [reen]
to walk
ṣe iṣẹ [shay ee-sheh]
do work
find more vocabulary at glosbe.com!